Abstract
Bínú bá ń bífá, Omo ̣ ̣ aráyé á fewúré ̣ dúdú bofá; ̣ Bínú òpẹ̀ lẹ̀ ̣ ò dùn, Omo ̣ ̣ aráyé a f`àgùtàn bòlọ̀ jọ̀ ̣ sètùtù; ̣ Orógbó pèlóbì le ̣ bọ ̣ Sàngó ̣ Bí Lakáayé ń bínú, Aráyé a fún un lájá je.̣ Ikú kò, ikú kò gbe ̣ bọ .̣ Sé bíkú bá je ̣ ja láyé ijó ̣ sí, ̣ Owọ́ ̣ ikú a máa gbòn iróró iróró, ̣ Bíkú bá jeku nígbà ìwásẹ̀ ,̣ Esẹ̀ ̣ rè ̣ a máa gbòn irìrì irìrì, ̣ Bíkú bá jeyin e ̣ lẹ́ bute ̣ , ara ikú a máa já ibùtè ̣ ̣ ibùtè,̣ Ikú àsìkò yìí bàjé ̣ kò gbebọ ̣ kò gbètùtù, Ìkà nikú, ikú kò màgbà béẹ̀ ̣ ni kò momo ̣ dé, ̣ Bílé oyin bá kan gbínrín gbínrín, Béẹ ̣ wádìí rè ̣ wò, isẹ́ ̣ ikú ni, Bódẹ̀ dẹ̀ ̣ `adò bá sì dibi ikorò, Ikú ló fa sábàbí è.
This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.