Adébáyọ̀ Fálétí Dará Ilẹ

Abstract

Àkàndé ìjí, Ọlọyẹ́ moyin òòò ́ Ojú kan ní í bíni Igba ní í woni dàgbà Ìwọ nìkàn, Elétùú, Ọdẹ orófó Mọlọyẹ́ moyin, Ọdẹ àdàbà ́ O jọgọrùn-ún baba fúnrúu wa ́ Ìwọ òjìnmí onímọ̀ àṣà àtèdè Ọ̀kàn ni mí lára òròmọdìẹ Tó ó kọ́ ní Fáfitì ẹlẹrankoòlúùbàdàn ́ Ọ̀kàn ni mi lára ọ̀jẹ̀ wẹwẹ ́ ́ olùwadìí Tó o bùn nímọ̀ mu Láti inú òdù àmù ikùn Baba onínúure, tó jàpapọ̀ baba ẹlòmíìn Baba mi, Pa-nílé-o-tó-roko Kò sí ká lọ ká bọ̀ lọrọ́ ̀ tirẹ Ìwọ lo pa, pa, pa Tó o pèyí tí í pa baálé rẹ ládìẹ jẹ o tó roko Kánmọ-ń-kíá lò ó dáni lóhùn ́ Ní gbogbo ọjọ́ tá a báwadìí wọ́dọ̀ rẹ Àkàndé, aráàjíléje

https://doi.org/10.32473/ysr.v3i2.130005
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...