Eré-onítàn Ìṣèlú Onírèké Òge gẹ́gẹ́ bíi Ìṣàfihàn Àléébù, Atọ́kùn Ìpèníjà àti ọ̀nà àbáyọ fún Ìṣejọba Nàìjíríà

Abstract

Bi eto-oselu awujo tabi orile-ede kan ba fe fese rinle pelu itesiwaju to jiire, o to, o si se pataki ki awon eniyan funra won finu-findo gbiyanju lati fi imo sokan pelu igbora-eni-ye nipa sise atunto lati le ri ojutuu si awon nnkan to baje nitori pe ko si ohun to baje koja atunse. 

https://doi.org/10.32473/ysr.v1i2.130153
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Copyright (c) 2021 Ayoola Oladunke Aransi, Hakeem Olawale

Metrics

Metrics Loading ...