Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Abstract

Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n koju awon oluko ati akekoo ede Yoruba ni orile-ede naa, ki o too wa wo sakun ojo-ola eto eko naa nile Amerika. Lara awon aba ti apileko yii gbe kale ki ojo-olo ede Yoruba le dara sii ni: kiko iwe ikoni to ba igba mu, to si see lo pelu imo ero, fifun awon akekoo ni imoran nipa iwulo kiko ede ajoji bi ede akonkunteni, fifi enu ko nipa fonti lati maa fi te Yoruba lori konputa ati odiwon fun ikoni lekoo, titi o fi kan ipese anfani fun awon akekoo lati lo si Naijiria nibi ti awon elede naa ti n lo o ni gbogbo igba.

https://doi.org/10.32473/ysr.v1i2.130150
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...