Àjùmọ̀ṣe àti Ìgbélárugẹ Èdè Yorùbá fún Ìkọ́ni ní oríṣiríṣi ẹ̀kọ́

Abstract

Ero mi ninu apileko yii da lori bi a se le saayan fun idagbasoke ede Yoruba de ibi wi pe yoo see se lati le fi ede naa ko eko yoowu ti o le je-yala sayensi ni o tabi eko oro-aje tabi eko oro-iisseelu. Awon ibeere ti o se pataki lati beere bi ise yii yoo ba di sise ni mo la sile ni sise-n-tele. Mo si fi lpe sita fun awon akomolede Yoruba lati tara si ise idagbasoke ede yi.

https://doi.org/10.32473/ysr.v1i2.130148
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...