Àìgbọ́ àti àìlèsọ èdè Yorùbá àti àbáyọ fún àwọn ọmọ Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Abstract

Ohun ti o je mi logun ninu apileko yii ni bi ogooro awon omo bibi ile Yoruba ni ile Amerika ko se le so tabi gbo ede Yoruba. Akiyesi mi ni pe, oro naa dabi oro amukun-un ti eru re ti wo lati ile ni. Mo salaye wi pe ainifee ede Yoruba lokan wa lara isoro ti o n koju opolopo awon omo bibi Yoruba ti won n gbe ni Amerika. Apileko naa gba gbogbo awon omo bibi Naijiria ni imoran pe o ye ki won nifee ede Yoruba, ki won si gbaruku ti kiko ede naa, papaa nipase iranlowo fun awon akomolede Yoruba. 

https://doi.org/10.32473/ysr.v1i2.130147
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...