Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá

Abstract

Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoruba, papaa julo nipa lilo awon ere idaraya keekeeke lori ero konputa fun kiko ede Yoruba. Ninu apileko naa, a safihan awon ere onimo ero gbajugbaja ti oluko le samulo won fun kiko ede Yoruba gege bii Jeopardy (Jeopaadi), Who Wants to be a Millionaire (Ta lo fe dololoa?), ati Wordsearch (Isawari Oro). Nipari, apileko naa se alaye to kun nipa arifani ati isoro ti o so mo awon ere ori ero wonyi. 

https://doi.org/10.32473/ysr.v1i2.130144
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...