Abstract
Wútùwútù yáákí;
Wútùwútù yám̀bèlé;
Ká súré pátápirá,
Ká fè wù àlàárì fọnkun àmódi; ̣
Ẹsẹ Ifá yìí jé ọ ̀ kan nínú àwọn ifá ńláńlá tí a fà yọ kúrò nínú Òtúá Méjì. Méjì ̣ ni àwọn onímò -èdè Yorùbá tó ti yẹ ẹsẹ Ifá wò fínífíní pe ̣ ̀ lú ìjìnle ̣ ̀ ìmọ̀ òde òní ̣ nípa èdè tí a ń pè ní lìǹgúísítíkì. Ẹni àkó kọ ́ , Ọ ̀gbe ̣ ́ ni ’Wáǹdé Abímbo ̣ ́ lá la ẹsẹ ̣ Ifá sí ò nà me ̣ ́ jọ.4 Ọlátúndé Ọlátúnjí ni ẹnì kejì; òun pín ẹsẹ Ifá sí ìsò rí méje.5 Gé gẹ ́ bí a ó ṣe rí i ní ìsàle ̣ ̀ (ẹ wo àlàyé 2), àwọn àye ̣ ̀ wò méjèèjì tí a dárúkọ ̣ wò nyí pọwo ̣ ̣ ́ léra. Nínú àdìtú wa yìí, ètò ẹsẹ Ifá onídàáméje ni a ó mùú lò nítorí pé ó dà bí ẹní bá ẹsẹ Ifá yìí mu jù lọ. Nínú ìdá èkìíní (Ìlà 1 dé 8), a lè pín àwọn gbólóhùn ibè sí oríṣìí meta.
This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.