Ògún: Bí a ṣe Fi Hàn Nínú Lítíréṣọ ̀

Abstract

 Ìtàn àbàláyé àwa Yorùbá sọ fún wa pé ògún ló ṣaájú gbogbo àwọn òrìsà yòókù nígbà tí wó n ń ti ìko ̣ ̀ lé o ̣ ̀ run bo ̣ ̀ wáyé. Òun ló ní àdá ti ó fi gán o ̣ ̀ nà ti ̣ gbogbo wó n gbà. Nítorí ìdí èyí, gbogbo àwọn irúnmale ̣ ̀ náà pẹnu po ̣ ̀ láti yan ̣ Ògún ni ọṣìnmalè , èyí ni olórí àwọn ìmọle ̣ ̀ , nígbà tí wo ̣ ́ n dé Ilé-Ife ̣ ̀ . Ṣùgbo ̣ ́ n ̣ ògún kò rójú jókòó sojú kan láti jẹ ọlá ti a dá a nítorí ìgbé ayé líle ti ó ti mó ọ ̣ lára àti iṣé ọdẹ tí ó ń ṣe. A gbo ̣ ́ pé èyí ló gbé Ògún de Ìrè. Nígbà ti yóò so ̣ ̀ kale ̣ ̀ ̣ láti orí òkè wọ ìlú Ìrè, kòṣẹ ni:

 Ọjó ògún ń ti orí òkèe bo ̣ ̀ ̣ Aṣọ iná ló mú bora Èwù e ̣ ̀ jẹ ̀ ló wo ̣ ̀ .

https://doi.org/10.32473/ysr.v6i1.130106
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...