Abstract
Onírúurú ìwádìí ló ti wáyé nípa ọdún ìbílè Yorùbá, ṣùgbó ̣ n, iṣé ̣ kò tíì pò ̣ lórí ̣ ipa àti ipò àwọn èwe nínú àjòdún ìbílè ̣ Yorùbá. Iṣé ̣ yìí lo àkójọ-èdè-fún-àyè ̣ wò ̣ láti inú Òrìṣà Ẹgbé tí ó jé ̣ ọ̀ kan pàtàkì nínú àwọn Òrìṣà èwe ní agbègbè Ye ̣ - wa-Àwórì, Ègbá àti Ìjè ̣ bú ní ìpínlè ̣ Ògùn láti ṣe àwárí ìmò ̣ lóri abala ibi tí iṣé ̣ àwọn onímò ìṣáájú kò tíì dé nínú lítíréṣò ̣ ọmọdé. Ìlànà tí a gbà ṣe iṣé ̣ ìwádìí ̣ yìí ni ṣíṣe àkójọ àwọn ìpohùn tí ó jẹ mó Òrìṣà Ẹgbé ̣ ní agbègbè Yewa-Àwórì, ̣ Ègbá àti Ìjè ̣ bú. A ṣe ìwádìí ló ̣ dọ̀ àwọn èwe tí wó ̣ n jé ̣ olùsìn àwọn Òrìṣà Ẹgbé ̣ ̣ yìí ní agbègbè Yewa-Àwórì, Ègbá àti Ìjè ̣ bú. A tún ṣe ìfò ̣ rọ̀ -wáni-lé ̣ nu-wò fún ̣ àwọn akópa tí wón jé ̣ àgbààgbà olùsìn Òrìṣà Ẹgbé ̣ náà ló ̣ lọ́ kan-ò-jò ̣ kan, a sì ká ̣ a sílẹ̀ nínú fọ́nrán àti fídíò. A tún ṣe àyẹ̀wò ìwé àpilẹ̀kọ, jọ́nà àti ẹ̀rọ-ayélujára lórí oríṣìí àwọn iṣẹ́ ìwádìí tó jẹ mọ́ lítíréṣọ̀ alohùn àwọn ọmọdé. Àwọn Ìpohùn tí a gbà jọ ní oko ìwádìí ni a ṣe ìtúpalẹ̀ wọn ní ìbámu pẹ̀lú àfojúsùn àwọn agbátẹrù ìfojú-ìmọ̀-ìbára-ẹni-gbépọ̀-wo-ìlò-àmì ti Amber àti Haque (2004). Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀wò ipò tí àwọn Yorùbá fi àwọn ọmọ wọn sí nínú ọdún ìbílẹ̀. Bákan náà ẹ̀wẹ̀, iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀wò ipa tí àwọn èwe àwùjọ Yorùbá ń kó nínú ìgbékalè ̣ ọdún ìbílè Òrìṣà Ẹgbé ̣ láwùjọ àwọn Yewa-Àwórì, È ̣ gbá and Ìjè ̣ bú. Iṣé ̣ yìí fi ̣ ìdí rè múlè ̣ pé, ipò pàtàkì ni ọdún ìbílè ̣ yìí wà nínú ètò ìgbé ayè àwọn olùsìn ̣ rè, tí wó ̣ n fi ń darí èròǹgbà wọn lórí ìfọkàntán, òtító ̣ ṣíṣe, ìdájó ̣ -òdodo, ìjúbà, ̣ dídarí-èmí wọn sí Òrìṣà Ẹgbé ̣ àti ìgbàgbó ̣ wọn nínú àyànmó ̣ . Iṣé ̣ yìí tún ṣe àfi ̣ - hàn àwọn ìdí pàtàkì tí wón fi ń ṣe ọdún ìbílè ̣ fún Òrìṣà Ẹgbé ̣ gẹ́ gẹ́ bí èyí tí wó ̣ n ̣ 294 Ishọla gbé àwọn ìpohùn inú rè kalè ̣ fún è ̣ kọ́ ẹ̀ sìn, ìwà ọmọlúàbí, àṣà àti ìṣe pè ̣ lú oríṣìí ̣ àwọn ìlànà ìbara-ẹni-gbépò fún àwọn ọmọ wọn.
This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.