Àkànlò-èdè Tuntun Nínú Àwọn Orin Ọ ̀ dọ ́ Ìwòyí

Abstract

Àkaǹlò èdè Yorùbá tuntun je ̣ ́ ìpèdè tí Àkànmú (2016) pè ní ìsọ ìgbàlódé tí ìtumò wọn loorìn díè tí ó sì ṣàjèjì sí àwọn tí ó máa ń ṣe àmúlò àkànlò èdè ti ̣ - wa-n-tiwa tí ó ti wà te ̣ ́ lè . Ọ̣ ̀pòḷọpo ̣ ̀ ̀ iṣe ̣ ̣ ́ ìwádìí ní ó ti wà lórí ìṣàmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin, fíìmù àgbéléwò, ìpolówó ọjà, ìròyìn, o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ nínú eré boòlù àfẹse ̣ ̣ ̀ gbá láàrin àwọn èrò ìwòran ní gbàgede ìwòran àti ìgbòkègbodò ọko ̣ ̀ ṣùgbó n kò fi bee ̣ ̀ sí iṣé tí ó jinle ̣ ̣ ̀ lórí ìjẹyọ àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin tàka-súfèé òde òní èyí tó wo ̣ ́ po ̣ ̀ láàrin àwọn o ̣ ̀ do ̣ ́ . Akitiyan láti dí àlàfo yìí ní ó bí àpile ̣ ̀ kọ yìí. Tío ̣ ́ rì èdè ojoojúmó (̣ Standard Language Theory) tí Mukarovsky ṣe agbáterù re ̣ ̀ ni a fi ṣe àtúpalè àwọn àkànlò èdè Yorùbá ̣ tuntun tí á yè wò nínú bébà yìí nítorí pé ó lè ṣàlàyé ohun tí ó je ̣ ̣ ́ kí àkànlò èdè Yorùbá tuntun yapa si èdè ojoojúmo ̣ ́ àti ohun tí ó ń fa ìyàtò gír ̣ íkì láàrin èdè ojoojúmó àti èdè ewì. A ṣe àṣàyàn o ̣ ̣ ̀ kọrin tàka-súfèé me ̣ ́ ta wonyi: Olátúnjí Ọládo ̣ ̀ tun À ̀làdé (Dotman), Azeez Fáṣọlá (Naira Marley) àti Oritse Fe ̣ ́ mi Má- je ̣ ̀ e ̣ ́ mite ̣ ́ Èkélè (Oritsa Fémi) nítorí pé àkànlò èdè Yorùbá tuntun farahàn púpo ̣ ̀ nínú orin wọn. Nínú ìtúpalè wa ni ó ti hàn pé àwọn o ̣ ̣ ̀ kọrin tàka-súfèé òde-òní fe ̣ ́ ràn láti máa ṣe àmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun bí i ‘oúnjẹ ọmọ’ (fún obìnrin tí ó ní ọyàn ńlá èyí tí ó bù kún ẹwà a rè ), ‘je ̣ ̣ ̀ wà’ (s ̣ ̀ ewo ̣ ̀ n), ‘ojúẹle ̣ ́ gba’ (oluko, ará oko èèyàn tàbí ẹni tí ojú re ̣ ̀ dúdú), ‘gbé bo ̣ ́ dì ẹ’ (lo ọpọlọ tàbí ọgbo ̣ ́ n orí ẹ) àti ‘yàúyàhúù’ (àwọn tí ó ń fi e ̣ ̀ rọ ayélujára lu jìbìtì) ge ̣ ́ ge ̣ ́ bí o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ àti ìdánilárayá. A ṣe àmúlò àfiwé ẹle ̣ ́ lo ̣ ̀ o ̣ ́ fún ìṣe ̣ ̀ dá àwọn àkànlò èdè Yorùbá tuntun tí ó jẹ yọ. Àfiwé ẹle ̣ ́ lò ọ ̣ ́ yìí náà ni ó bí ìsọdorúkọ, fìrósínròójẹ àti àwọn èròjà ìṣe ̣ ̀ dá o ̣ ̀ ro ̣ ̀ mìíràn tí a lò nínú àpile ̣ ̀ kọ yìí. Ó hàn gbangba pé àkànlò èdè Yorùbá tuntun rẹwà jù lọ fún ìbáraẹniso ̣ ̀ ro ̣ ̀ , ṣíṣe àlàyé o ̣ ̀ ro ̣ ̀ , àpèjúwe àti ìdárayá nínú orin tàka-súfèé

https://doi.org/10.32473/ysr.v6i1.130096
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...