Abstract
Òwe jé ọ̀ nà tí à ń gbà láti ṣe àfihàn ìgbéayé è ̣ dá, ìgbàgbó ̣ , àṣà àti ìṣe àwọn ̣ ènìyàn nínú àwùjọ. Saájú kí ètò mò-ọ́ n-kọ, mò ̣ -ọ́ n-kà tó wọ àárin àwọn ènìyàn ̣ dúdú ni ìran Yorùbá ti ní àfojúsùn onírúurú ọgbón ìkó ̣ nilédè abínibí èyí tí wọn ̣ ń ṣàmúlò láti kó tèwe-tàgbà nílànà bí wọn ṣe lè gbé ilé ayé ìrò ̣ rùn pè ̣ lú ìfò ̣ kàn ̣ - balè. Ní àwùjọ Yorùbá gé ̣ gẹ́ bí àwùjọ mìíràn láàrin àwọn è ̣ yà ènìyàn dúdú ní ̣ ilè Ááfíríkà, òwe jé ̣ ilé ìsura ọgbó ̣ n, ìmò ̣ àti òye èyí tó jé ̣ ọgbó ̣ n ìṣàmúlò fún ̣ tawo tògbè ̣ rì láti máa fi kó ̣ àwọn ènìyàn ní ìmò ̣ ìjìnlè ̣ èdè abínibí wọn. Iṣé ̣ yìí ̣ ṣe àfihàn onírúurú ìlànà tí a lè lò láti fi òwe Yorùbá ṣe ìdánilékọ̀ ọ́ tó yè kooro ̣ ní ìbámu pèlú ìgbà àti àsìkò lílo ò ̣ kọ̀ ọ̀ kan wọn àti oríṣìíríṣìí ọgbó ̣ n tí ènìyàn lè ̣ kó nípa ìfòwekó ̣ nilé ̣ kọ̀ ọ́ èyí tó lè mú kí ènìyàn jìnnà sí jíjìn sí ̣ ọ̀ fìn ayé, láti ní àfojúsùn ohun rere àti láti fakọyọ níbikíbi láìmù ìpalara lówọ́ . Ní àfikún, pépà ̣ yìí ṣàgbéyèwò ohun tí òwe jé ̣ , onírúurú ò ̣ nà tí a lè gbà ṣe ìdánilé ̣ kọ̀ ọ́ nílánà ̣ abínibí fún tèwe-tàgbà àti onírúurú ìsòrí òwe fún ìdánilé ̣ kọ̀ ọ́ . Tíó ̣ rì lámèyító ̣ ̣ ìfojú-àṣà-ìbílè-wo ni a lò gé ̣ gẹ́ bí ò ̣ pákùtè ̣ lẹ̀ fún iṣé ̣ yìí.
This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.