̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá

Abstract

 Ìtànkálẹ̀ èrò ẹni tí ọ̀ pọ̀ lọpọ̀ omímọ̀ gbà bí èrò òdì ìpọ́ nrọ́ léwé tàbí irọ́ nípa tó lóòrìn láwùjọ, bákan náà, ni ó sì jẹ́ ohun èlò pàtàkì nínú ìgbékalẹ̀ fíímù Yorùbá. Is̩ é ̩ ìwádìí lórí ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni àti ìbás̩ epò̩ rè ̩ pè ̩ lú ìs̩ e-o̩ kàn kò tí ì pò̩ tó nínú fíìmù Yorùbá, èyí ni is̩ é ̩ yìí tànmó̩ lè ̩ sí. Tíó̩ rì aje̩ mó̩ s̩ e-o̩ kàn tó dá lórí ìko̩ lura ninú o̩ po̩ lo̩ àti ìs̩ àkóso rè ̩ ni a lò, èyí tó s̩ àfihàn wíwá ìtumò̩ ìjìnlè ̩ sí ìhùwàsí ènìyàn. A s̩ àmúlò fíìmù méje kan tí a mò̩ -o̩ ́ n-mò̩ s̩ àyàn fún ìtúpalè ̩ nítorí wó̩ n kún fó̩ fó̩ fún kókó tí is̩ é ̩ yìí dá lé. A wo àwo̩ n fíìmù yìí, a sì s̩ e àdàko̩ àti ìtúpalè ̩ wo̩ n fínnífinní. Ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni farahàn nínú ètò ìs̩ èlú/is̩ è- jo̩ ba, è ̩sìn, ìlàsílè ̩ às̩ à àti nínú orúko̩ ìyàsó̩ tò̩ /ìfè ̩ gànpeni. Àbùdá àdámó̩ , ìlera o̩ po̩ lo̩ , ìrírí ìgbà èwe àti ìhùwàsí aje̩mó̩ s̩ e-o̩ kàn a máa nípa lórí às̩ eyo̩ rí tàbí ì- jákulè ̩ ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni.

https://doi.org/10.32473/ysr.v6i1.130092
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.