Àfìhàn Àwo̩ n O̩ lo̩ ́pàá Oríle̩ ̀-èdè Nàijíríà Nínú Às̩ àyàn Lítírés̩ o̩ ̀ Àpile̩ ̀ko̩

Abstract

Àjo̩ o̩ lo̩ ́ pàá orílè ̩-èdè Nàijíríà je̩ ́ àjo̩ tí a dá sílè ̩ láti máa mú kí omi àmù ìlú tòrò. Onírúurú is̩ e̩ ́ akadá tó ti wáyé lórí wo̩ n bu e̩ nu àte̩ ́ lù wo̩ ́ n. Àmo̩ ́ , àwo̩ n òǹko̩ ̀ wé lítírés̩ o̩ ̀ àpilè ̩ ko̩ èdè Yorùbá nínú ìwé wo̩ n fìdí rè ̩ múlè ̩ pé, àwo̩ n o̩ lo̩ ́ pàá ní àwo̩ n ìpènijà tó ń bá wo̩ n fínra lábe̩ ́ lè ̩ ; àwo̩ n ìpènijà be̩ ́ è ̩ ni pépà yìí dá lé. Tío̩ ́ rì Sos̩ ío̩ ́ lo̩ ́ jì lítírés̩ o̩ ̀ Yorùbá ni a lò. Ìwé ìtàn àròso̩ marun-un, eré- onítàn me̩ ́ fà àti ewì meji la s̩ àtúpalè ̩ . Àwo̩ n ìpènijà tí a hú jáde ni: o̩ ̀ ro̩ ̀ ako̩ -n[1]bábo, àìní ìlapa ètò òun irins̩ é ̩ tó mú yányán, àìsí ètò amáyéde̩run tó fún àwo̩ n o̩ lo̩ ́ pàá, irú ìjo̩ ba tàbí àwo̩ n olórí o̩ lo̩ ́ pàá tó wà lóde àti ìwà òbìlè ̩ je̩ ́ láàárín àwo̩ n o̩ lo̩ ́ pàá fúnra wo̩ n. Iṣẹ́ yìí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé tí a bá wá ojútùú sí àwo̩ n ìpènijà òkè yìí, àjo̩ ̀ o̩ lo̩ ́ pàá orílè ̩-èdè Nàìjíríà yóò túbo̩ ̀ lè ta bíó̩ bio̩ ́ sí i le̩ ́ nu is̩ é ̩ wo̩ n.

https://doi.org/10.32473/ysr.v6i1.130090
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.