Àgbéyẹ ̀wó Ìfẹ ̀tọ ́dunni àti Ìdájọ ́ Nínú Àsàyàn Eré-onítàn Yorùbá

Abstract

 

Ìfè tọ ́ dunni àti ìdájo ̣ ́ kó ipa pàtàkì nínú iṣe ̣ ́ àwọn òǹko ̣ ̀ wé alátinúdá láti ìgbà ̣ pípé wá àti títí di àkókò yìí. Bí àwọn iṣe ̣ ́ wo ̣ ̀ nyí ṣe po ̣ ̀ tó, ìwà o ̣ ̀ daràn àti ìdájo ̣ ́ ̣ kóòtù ni iṣẹ́ àwọn onímọ̀ tó ṣaajú fúnkamó jùlọ láì ka àwọn o ̣ ̀ nà ìfe ̣ ̀ tọ ́ dunni àti ̣ oríṣìí ìdájó mìíràn tó ń wáyé kún bàbàrà. Nítorí náà, a lo Ìkéde Àjọ Àgbáye àti ̣ Òfin Orílè èdè Nàìjíríà ti ọdún 1999 ge ̣ ́ gẹ ́ bí àte ̣ ̀ gùn láti ṣe àgbéye ̣ ̀ wò ohun tí a ̣ ń pè ni ìfè tọ ́ dunni, ìbáṣepo ̣ ̀ àti ìdájo ̣ ́ ge ̣ ́ gẹ ́ bí ó ṣe hàn nínú àwọn àsàyàn ìwé ̣ eré onítàn méje tí a mò -ọ ́ n-mọ sàyàn fún àgbéye ̣ ̀ wò. Èyí ni láti fi ìdí ìfe ̣ ̀ tọ ́ dunni ̣ múlè àti ìbáṣepo ̣ ̀ tó wà láàrin afe ̣ ̀ tọ ́ dunni àti ̣ ẹni tí a fè tọ ́ dùn nípase ̣ ̀ ìṣe ̣ ̀ dánìyàn, ̣ ọjó orí, e ̣ ̀ sìn, ipò àti àwọn o ̣ ̀ nà ìdájo ̣ ́ . Àwọn ìwé náà ni: Akínwùmí Ìṣo ̣ ̀ lá (1970) ̣ Ẹfúnṣetán Aníwúrà, TAA Ládélé (1971) Ìgbà Ló De, Adébáyò Fálétí (1972) ̣ Baṣò run Gáà, ̣ (1980) Wó n rò pé wèrè ni, ̣ Láwuyì Ògúnníran (1977) Ààrẹ-Àgò Aríkúyẹrí , Adéṣọlá Ọláté jú (2009) ̣ Iná Ràn àti Agboọlá Àyándìran (2016) Ààrò Wò rọ ̀ kọ ̀ .̣ Tíó rì Máàsì to níí ṣe pe ̣ ̀ lú ìbágbépo ̣ ̀ ẹ ̀ dá ni a fi ṣe òsùnwo ̣ ̀ n nítorí ̣ pé ohun gbogbo tí ó ṣẹlè nínú àwọn ìwé náà j ̣ ẹ mọ ìjẹgàba, ìré nij ̣ ẹ, ìjàfé tọ ̀ ọ ́ ̣ẹni. Ìwádìí fi hàn pé afé ayé, ìṣèlú, ọro ̣ ̀ ajé àti ìsinúbí ní ó je ̣ ́ okùnfa ìj ̣ ẹgàba èyí ti 2 Adéjùmò & Ṣàngótóye ̣ ó sì yọrí sì ìpànìyàn, ìbínú-òdì, ìfiniṣètùtù ọla, ìjínigbégbowó, ìfìyàjẹọmọdé, ìfọmọsòwò, ìmúnitìmó lé lo ̣ ́ nà àìto ̣ ́ , ìfiniṣerú àti ìfipámúnisìn Àwọn e ̣ ̀ tọ ́ mìíràn ̣ tí wọn tún tè lójú ni e ̣ ̀ tọ ́ ìwàláàyè, òmìnira ìdágbé, ìyì ọmọnìyàn, ìyanfanda ̣ àti ìkórajọ. Àbájáde ìwádìí láti inú àwọn ìwé eré onítàn tí a lò fún iṣẹ́ ìwádìí yìí fi yé wa pé́ ìfè tọ ́ dunni kò ní ṣe pe ̣ ̀ lú e ̣ ̀ dánìyàn tàbí e ̣ ̀ sìn ̣ ẹni tí wó n t ̣ ẹ è tọ ́ rẹ ̀ ̣ lójú. Ìdájó oríṣìí me ̣ ́ ta to farahàn nínú iṣe ̣ ́ yìí ni ìdájo ̣ ́ kóòtù, ìdájo ̣ ́ lọ ́ nà ìbíle ̣ ̀ ̣ àti ìdájó tìpátìkúùkù- mímú òfin lò lo ̣ ́ wọ ́ ara ̣ ẹni. Ìgúnlè iṣe ̣ ́ ìwádìí yìí ni pé ̣ ò rọ ̀ ìfe ̣ ̀ tọ ́ dunni àti ìdájo ̣ ́ kò j ̣ ẹ àjèjì ni àwùjọ Yorùbá, o ti wà nínú àṣà Yorùbá kí àwọn oyinbo tóó gòkè. Ìfè tọ ́ dunni ti a kò ba tètè mójútó le ṣe okùnfà òmíràn ̣ tí ó burú ju tàkó kọ ́ lọ, ṣùgbo ̣ ́ n ìdájó tìpátìkúùkù kò dára. Ìlànà ìbíle ̣ ̀ àti òfin ló ̣ dára jùlọ láti jà fún è tọ ́ ̣ẹni.

https://doi.org/10.32473/ysr.v6i1.130087
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...