A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language

Abstract

OF: Èdè Yorùbá ni á ̀kóko yìí tí ̀ ń lọ sí òkun ìgbàgbé, níbo ni ọr̀ ọ yìí tí w ̀ ọ wá?

TF: Hmm, ìbéèrè tó ṣe kókó tó ṣe pàtàkì tó ń kọni lóminú rèé. Lotitọ, èdè abínibí wa Yorùbá ti ń parun, àwọn oun tó sì fàá pọ̀ lọṕ ọ̀lọpọ. À ̀kọ́kọ́ ni ipò ti ède ̀ Gẹẹ̀ sí ̀ ni ́ ori ́lè e ̀de ̀ wa Nài ̀jirí yá . Ipo ̀ ̀ yíì jẹyọ lati ipa ìj ́ ọba awon ̀ Birìtìko ̀ ́ loriwa kí a to ́ ́ gba ominira a ̀ ti a ̀ won funfun tí w ̀ ọn gbe ́ ́ ìmọ̀ẹsìn wa ̀ . ́ Aẁ ọn wọnyi ̀ ́ ni wọn k ́ ọ́kọ́ gbé ẹsìn ìgba ̀ gb̀ ọ́ ati ̀ ẹ̀kọ́ mọọ̀ ́kọ mọọ̀ ́ka. Wọn ́ bẹr̀ ẹ̀ síní ma kọ́ aẁ ọn ará Yorùbá ni e ̀dè Gẹẹ̀ si ní ile ́ ́ ìwéṣugb̀ ọn a ko ́ ̀ le ̀ so wipé ́ wọn ́ ṣe eyi ̀ ́ ki e ̀dè Yorùbá le ̀ parun. Ìdi ́ ti ́ mo f sọ eyi ̀ ́ ni wipé ́ aẁ ọn ti ́ wọn gbe ́ ́ ẹsì n i ̀ gba ̀ gbo ̀ ́ yi ̀i ́ wá naá ̀ lóṣe igbi ̀ yà nju ̀ ́ lori bi ́ ́ ède ̀ Yorùbáṣe kókó di ki ́kọ si ́lẹ. ̀

Nígbà tí aẁ ọn Bìrìtìkó dé lati wa ́ ́ ma ṣe ìjọba amunisi ́ n, i ̀ ̀jọba atò ̀kerè wa ̀ ́ lẹyìn tí o ́ wo ̀ ̀ amuni ́ ṣẹrú dé opin, e ̀ ̀dè Gẹẹ̀ sì yíì ni w ́ ọn ́ f ń darí wa. Oun ti ̀ wọn ́ f ń kọ́ aẁ ọn ọmọ Yorùbá tó jẹ́ akẹẹ́ ̀kọ́ ni ́ẹ̀kọ; ò un ni w ̀ ọn ́ f ńṣe etò ̀ of̀ n, oun na ̀ á ̀ sìni wọn ́ f ṣe etò ̀ kará ̀katá . È yí tu ́ ḿ ọ̀ si ́ wipé ́ẹnikẹni to ́ ́ bá fẹ́ rí ọwọ́ mun nigba ́ ̀ naa gbọdọ le sọ e ̀dè Gẹẹ̀ si. E ́ ̀dè Gẹẹ̀ si yi rí iha pa ́ tà ̀kì yii gba nitori ́ pé ́ oun ni e ̀ ̀dè tó pa gbogbo wa pọ̀ nigba naa torí gẹǵ ẹ́ bi ́ gbogbo wá ṣe mọ, ori ̀ ́ṣiri ́ṣi ati ̀ ọp̀ ọ̀lọpọ̀ e ̀dè abinibi ́ ́ ni ó wà ni orílẹ̀ e ̀dè Nài ̀jirí yá . ̀ Ati igba ̀ yi ni e ̀ ̀dè Gẹẹ̀ si ti j ́ ẹ gàba lori a ́ won e ̀ ̀dè abínibí wa.

Ohun mirá n to ̀ ́ ń mú ìparun bá èdè Yorùbá ni aẁ ọn ìjọba wa. Lẹyìn tí a ́ gba ominira, e ̀ ̀dè yíì ṣi wà pẹ̀lu wa títí di oní. Ipo ̀ ̀ gíga tí ó wà nọni o ́ ́ṣì wa. ̀ Òun ni èdè ìdarí ìjọba, oun ni e ̀ ̀dè of̀ n wa. Kó dà iwe of̀ n tó ga jùlo ní ilu wa e ̀dè Gẹẹ̀ si ni w ́ ọn ́ f kọ. Ni toot ́ ọ, o ma ṣoro fu ̀ n ìj ́ ọba apap ̀ ọ̀ láti mú èdè kan ṣoṣo ninú ́ oríṣiríṣi ede to n be ni ilu wa, eyi lo faa ti èdè Geesi ti ko je ti eya kankan f jẹ aaỳ ò ̀ wọn. Ṣugb̀ ọn a ́ ẁ ọn adari ́ ni ́ ipi ̀ nl ́ ẹ̀ tó jẹ́ ti Yorùbá 1 . Tis essay was originally published in Gbe ́legb́ ọ́ a Yoruba weekly magazine issue of March 23-29, 2020. 322 Oyesina Fadare lèṣe aẁ ọn nǹkan tó le mú agbega ba ̀ ́ èdè Yorùbá. Bi ́ owe a ̀ ẁ ọn baba wa, ti ́ọr̀ ọ̀ bá kan òke ̀ tó kan ilẹ, ò ́ ni ́ ibi ̀kan à ń gbe si. Á ẁ ọn olorí ́ ilẹ̀ Yorùbá gbọ́dọ̀ mọ̀ pé àì fun li ́ ́lo èdè Yorùbá ni ́ ipò ti ́ yanranti ́ ninú ́ i ̀ṣèjọbà kò jẹ́ kí ó wun ará ìlú lati ma ́ a lo. Ede G ́ ẹẹ̀ si ti di e ́ ̀de ̀ apà pà ndodo fun a ̀ ̀ṣeyọrí ni ́ ori ́le ̀ e ̀dè wa.

Yat̀ọ sí íj ̀ ọba, aẁ ọn òbi naá ni ̀ nn ́ ̀kan ṣe pẹ̀lúọr̀ ọ tò wa ́ nil ̀ ẹ yi. Aẁ ọn òbí ayé òde oni ̀ ́ kìí sọ èdè Yorùbá si awọn ọmọ wọn. Wọn ní ìgba ́ gb̀ ọ́ pé èdè abinibi ́ ma ́ ṣe àkóbá fun mím ́ ọ e ̀de G̀ ẹẹ̀ si; a ́ ti wi ̀ pé Ǵ ẹẹ̀ si si ́ ṣe patà ̀kì ju e ̀de ̀ abinibi ́ ́ lọ. Ihà tí wọn k ́ ọ sí e ̀dè abinibi ́ ́ kò da rará ; ẃ ọn rí bíi ede ara ́ ́ oko. Wọn gbagb ́ ọ pe ti ọmọ bá ti mọ e ̀dè Gẹẹ̀ si, o ́ ́ ti kogo ja; ko ́ ̀ sí ipò ti ́ kò le ̀ dé ni aye ́ . Ile ́ í we to n ko ̀ ọmọ ni ede Gẹẹ̀ si ni ́ ̀kan ni won ma n fẹ ra ́ n a ́ ẁ ọn ọmọ wọn lo. Gbogbo eerò ̀ burúkú wọnyi ̀ ́ ni wọn ́ f si ́ awon ọmọ ninu ti wọn ó si ̀ ma dagba ̀ là ti ko ́ rira e ́ ̀de abi ̀ nibi ́ . É yi ̀ ló fá ti ̀ é ̀de Yoru ̀ ̀báf n re ko ́ tò . Oo ̀ ̀ṣà tí á n bọ tí a kòf han ọmọ, ṣé ìparun rẹ̀ ò ma kan d ̀ ẹ̀dẹ?̀ Aẁ ọn ti ́ mo tun ma ni ́ ́ wọn ́ ṣe okunfa ̀ ̀ iparun e ̀ ̀dè abinibi ́ ́ bi ́i Yorùbá ni aẁ ọn olùkọ́ ati olu ̀ ̀dasíl ́ ẹ̀ ile iwe. Lati ́ ẹ̀kọ́ ìbẹr̀ ẹ̀ ni wàhálà yíì ti f́ ojú han. ̀ Ède G̀ ẹẹ̀ si ni olu ́ ̀kọ ma n ́ ló fù n ́ ọp̀ ọ̀lọpọ à ẁ ọn im̀ ọ̀ẹ̀kọ. Iye a ́ ̀kóko tí w ̀ ọn ́ f ń kọ́ e ̀dè Gẹẹ̀ si ju a ́ ̀kókò ti won f sílẹ̀ fún e ̀dè abinibi ́ ́ lọ ni ìlọpo ìlọpo. Kó dàẹ̀ṣẹ̀ ńlá ni ti akẹẹ́ ̀kọ̀ bá ń sọ e ̀dè Yorùba.

 

 

https://doi.org/10.32473/ysr.v4i2.130055
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.

Metrics

Metrics Loading ...